Jump to content

Adaora Udoji

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adaora Udoji
at the Montclair Film Festival, photo by Neil Grabowsky, 2019
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kejìlá 1967 (1967-12-30) (ọmọ ọdún 57)
United States
Ẹ̀kọ́University of Michigan,[1] University of California, Los Angeles, School of Law
Iṣẹ́Adjunct professor at NYU
Ìgbà iṣẹ́1995–present

Adaora Udoji (tí a bí ní 30, Oṣù Kejìlá, Ọdún 1967) jẹ́ oníròyìn àti agbéròyìnjáde

Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀rí, ó jẹ́ olórí asọ̀tàn ni Rothenberg Ventures àti ààrẹ fìdíhẹẹ́ tí ilé ìṣe tuntun tó dá lórí imọ ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ News Deeply, tí Time magazine pè ní, "ọọ̀jọ̀gbọ́n alafikun [2] Ó ti ṣiṣé gẹ́gẹ́ bíi ọmọ-ẹgbẹ́ ààjọ ti Montclair Film Festival[3] ati ààjọ olùbádámọ̀ràn àwọn obìnrin ní NBCUniversal.[4] Ó sì tún jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Woodrow Wilson, lẹ́yìn èyí ni ó dá Boshia Group sílẹ̀,[5] akojopo àwọn amoye tó ń ṣíṣe eto àkóónú àti isise, àwọn agbéròyìnjàde network of content and operational strategists, producers àti àwọn olùsọ̀tàn.

Ó wà lára àwọn ìgbìmọ̀ kékeré oníròyìn tí wọ́n ti ṣiṣẹ́ ìròyìn orí afẹ́fẹ́ àti ẹ̀rọ àtagbà, pẹ̀lú ẹ̀rọ rédíò gbogboogbò. Ó sì wà ní ara àwọn ogún áńgẹ́lì aláwọ̀ dúdú tí ó yẹ ní mímọ̀ fún àwọn ilé ìṣe tí wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ ń dìde bọ̀. (20 Black Angels Worth Knowing For Minority Startups) .[6][7][8]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Adaora Udoji". Pipeline Fellowship. Archived from the original on February 25, 2016. Retrieved February 18, 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Meet The Inspiring Woman Breaking News About Syria As She Reinvents Digital Journalism". FastCompany.com. September 11, 2013. Retrieved December 18, 2017. 
  3. "Who We Are | Montclair Film Festival". montclairfilmfest.org. Archived from the original on 4 October 2014. Retrieved 17 January 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "News - NBC Universal Careers". Nbcunicareer.com. Retrieved February 18, 2016. 
  5. "As Virtual Reality Content Gains Traction, Bigger Dollars Flow to Ad-Tech Players". September 14, 2016. 
  6. "20 Black Angels Worth Knowing For Minority Startups - Black Enterprise". www.BlackEnterprise.com. May 9, 2014. Retrieved December 18, 2017. 
  7. Udoji, Adaora (2017-12-06). "I was a co-host with John Hockenberry on WNYC. The experience was scarring | Adaora Udoji" (in en-GB). The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/world/commentisfree/2017/dec/06/john-hockenberry-wnyc-investigation. 
  8. Ryan, Lisa (2017-12-06). "Public-Radio Icon's Former Co-Host Opens Up About His Harassment of Her" (in en-us). https://www.thecut.com/2017/12/john-hockenberry-adaora-udoji-harassment-wnyc.html.